11/09/2012

Munachi Abii: Se aye jije naa ni eleyi?


Ejowo, iru owe yoruba wo lo ye fun iru aworan yii? Arabinrin yii ni oruko re n je Munachi Abii, o sese di
omo odun meedogbon ni o. N je iru imura bi ti were yii wa bojumu to ni awujo wa yii? Bo ya ko ba ti e wule bo tan pata-pata ni ki gbogbo aye le ri gbogbo oun ti o ta.

O mu mi ran ti orin kan ti a ma n ko fun iru eni ti o ba mura bayi ni aarin
awujo.

"Osi re e wa ra, eyin okunrin
Adanu re e wa ra eyin okunrin
Ko gbowo, ko gbobi loja ti tawa
 - Loja ti tawa o, loja ti tawa
   Ko gbowo ko gbobi, loja ti ta tawa".

Aso bi ti eni ti o ku die kaato fun yii ni Munachi wo lati fi se ayeye ojo ibi re, e ri wipe ile aye ti n dori kodo.
Bee, obi kan naa lo si bi omo yii o, inu ebi kan naa losi ti jade wa, se ko ni onibawi ni, abi enu o ka?

No comments:

Post a Comment