Mo
lero wipe o ti wa to gee bayi, nitori wipe o ti wa di iba isele baraku fun mi
bayi de ibi wipe bi oko mi ba wa ninu ile gan, emi ati aburo oko mi a ma sare
'gbose' ara wa wo ni kanmo-nkebe. Iberu okan mi bayi wa ni wipe bi a ba n ba lo
bayi, oko mi ko ni pe ti yoo fi fura ohun ti o n sele laarin emi ati aburo re.
Ka
ma paro, ka ma se eke, o da bi enipe mo ti jingiri ninu iwa ibaje ti ko dun gbo
leti yii. Nitori wipe ipele ti n o ki n le de ti emi ati oko mi ba jo n sere
ife, mo ma n ko ibe ni ilopo pupo nigba ku gba ti emi ati aburo oko mi ba jo n
'ro ibon mi' fun ra wa. Ori mi asi ma kanrin gidigidi agaga ti o ba ti je wipe
to ni kia-kia ti o ti mo wa lara ni a sare waaye fun, iyen ni kan to bu omi rin
oungbe ibalopo gege bi loko-laya tii ba ma gbe mi ni akoko na.
Aburo
oko mi yii da pe lokunrin, odun wo, o se ri moni, awomalelo, awo tun wo pada
seyin ni, bo ti le je wipe n ko le gba okunrin miran laaye lati ba mi ni
ajosepo, aburo oko yii duro dede, idi re niyi ti mo fi ma n gba aburo oko mi
yii laaye.
Nigba ti mo se alabapade oko mi yii ni iwon bi odun meewa seyin, mo mo daju wipe iru okunrin ti mo nife si niyi lati fi se ade ori, tori wipe mo gbadun ere ife ti akoko jo se de bi gee, o temi lorun gidi gan-an ni ni ale ojo ti mo n so yii.
Awa mejeeji pade ara wa ninu okan ninu awon ile iwe giga fasiti ni oke oya. A si se igbeyawo ni nkan bi odun meta seyin, emi si ni eleyi ti mo wa n wo ijakadi pelu ogun abele ti o ti di iba isele baraku fun mi yii. Mo mo wipe ohun ti ko da rara ni ohun ti mo rawo le yii, amo, o nira fun mi lati gba ara mi kuro ninu iwa ibaje yii
Mo
ti pinnu ninu okan mi wipe mi o ni 'fi obe eyin je oko mi nisu' ni ona yoo ti
iba je, sugbon nigba ti aburo oko mi yii pari eto eko re ni ile iwe giga
fasiti, o wa bere si ni ba wa gbe papo ni odun to koja yii. Leyin osu meji ti o
dase wo inu ile wa ni ilu ti yii, ti ori mi si ti yi pada. Isele biba ara wa ni
ajosepo yii bere logan ti oko mi lo irin ajo kan lati ibi ise re.
Oru ojo ti oko mi lo si irin ajo yii ni o ibalopo gege bi toko-taya yii kan sa dede beere laarin wa. N ko ni le ma salaye bi eran ti o mu ere run se mu gbegiri san, tori wipe mo da ara mi lebi bi gbogbo nkan se sele leyin oru ojo naa.
Oro yii wa jo di mosinu-mosikulaarin emi ati aburo oko mi, awa mejeeji wa jo n se bi enipe nkankan o sele laarin wa, amo lati igba yen lo bayi, 'kaka ki o san lara omo iya aje awa mejeeji, nise ni o kan n fi gbogbo omo bi obinrin', nitori wipe nigba ti oko mi pada de lati irin ajo re, o ti wa di nkan inira fun lati gbadun oko mi nitori wipe tibi-tibi re ko ka mi lenu mo, aburo oko mi ti je ki enu mi o fe. Oko mi ko wa le temi lorun daada mo bi aburo re se n te mi lorun nigba gbogbo. Eleyi gan-an lo wa je ki aparo mi o wa taku si orun isu aburo oko mi.Opo igba lo je wipe nise ni ma yo kele-kele loru kuro legbe oko mi lori ibusun wa lo si yara itura (nibi ti a ti ma n wu iwa ibaje wa yii) bi eni pe mo fe lo se igbanse tabi lo to.
Nise ni mo ma n momo ji oko mi nigbati mo ba ti ri wipe orun ti wo lara tan wipe mo fe lo si yara itura, gbogbo, igba si ni mo ma n ri wipe mo tete pada laarin iseju marun, amo ki n jewo fu yin, pelu inu didun ati itelorun ni mo se ma n pada si egbe oko mi lori ibusun wa.
Diedie ni mo bere si di eni ti iyi re ti n din ku, ayo mi si bere si ni baje lo gege bi iyawo ile nitori awon ohun ti o n sele yii. Nitori wipe o ti e ti wa di nkan ojoojumo laarin emi ati aburo oko mi lati igba ti o ti di wipe mi o lo sidi okowo mi mo, latari isele jagidijagan ti o n fi ojoojumo sele ni agbegbe ile itaja mi. Eyi lo fa to fi je wipe emi ati aburo oko mi nikan ni a ma wa nile lati aaro. Paapaa, bi mo se n ko iwe yii, ko si idaniloju wipe kii se gbogbo ojo oni ni a fi ma 'yata yayo yoya' Inu mi ko lati te siwaju ninu iwa palapala yii, bee, n o si mo bi mo se le so jade fun oko mi wipe bayi kasa, bayi kawodi. Bee mo si tun mo daju wipe ni ojo ti asiri ba tu sita tabi si lowo, ko b'esu b'egba ti yoo fi le mi jade kuro ninu ile re. Mi o ni so fun, nitori mo gbodo daabo bo igbeyawo mi. Pabanbari re wa ni wipe, aburo oko mi ko ti e wa fi igba kan ri wipe ohun ti ko dara ni oun n se yii, nise ni okan re bale lori iwa ibaje ti awa mejeeji n wu niwa yii.
Eyi
to wa buru nibe bayi ni wipe, igba ku igba ti idake roro ba ti wa bayi, paapaa
julo ti a ba jo wa papo, ti a si wo oju ara wa, nise ni a kan ni jo mo bi awa
mejeeji yoo se le papo ni.
Eyin
ti e n ka nipa mi yii, ejowo, iranlowo yin ni mo fe. Kini yoo je ona abayo kuro
ninu isoro ti mo ko ara mi sii yii?
N
je kii se wipe ejo oro mi ni owo ninu? Se oju lasan ni a bi o ju oju lasan lo?
Mo fe amoran tooto lati enu yin. Mo gbodo wa ona abayo nitori wipe n ko le ma
ba lo bayi, bo tile je wipe emi tikalara mi ko ni ojutu si oro naa.
Oro lati enu olootu:
E jowo bi a ba se n da si oro yii, e ma se je ki a ma sepe tabi so oro kobakungbe si eni yii, ko si eni ti o ko ja asise ati wipe teni tode loni lari, a mo eniti yoo kan to ba di ola. E je ka ri eni yii gege bi eniti o je eje wa ti a si fe fa jade kuro ninu wahala afowofa ti o ti ko ara re si. E se pupo.
E jowo bi a ba se n da si oro yii, e ma se je ki a ma sepe tabi so oro kobakungbe si eni yii, ko si eni ti o ko ja asise ati wipe teni tode loni lari, a mo eniti yoo kan to ba di ola. E je ka ri eni yii gege bi eniti o je eje wa ti a si fe fa jade kuro ninu wahala afowofa ti o ti ko ara re si. E se pupo.
No comments:
Post a Comment